Ohùn tí a bá fi pe ọ̀rọ̀ Yorùbá ní àmì orí irú ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀. Ẹ ṣé pùpọ́ fún ẹ̀kọ́ iyebíye yìí. Ǹ ẹ mọ̀ pé ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ Yorùbá tàbí ẹni tó mọ èdè Yorùbá ni kò mọ àmì orí-ọ̀rọ̀ Yorùbá.
@olujideolumofe2278
2 жыл бұрын
Olùkọ́, ẹ ṣeun. Àǹfàfìní pọ̀ nínúu mímọ Àmì Ohùn. Áá jẹ́ kí èdè Yorùbá yéni yékéyéké. Áá jẹ́ kí a mọ ìtumọ̀ ọ̀rọ̀. Áá jẹ́ kí a le ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀. Áá jẹ́ kí á mọ ohùn ìlú. Áá jẹ́ kí a morin-í kọ́. Áá rànwá lọ́wọ́ láti le ṣàlàyé yéni yékéyéké.
Пікірлер: 7