ARAKUNRIN ADENIYI MOSES ti o je onimo nipa eto oro aje ati oselu sapejuwe owongogo onida mokanlelogota (61%) to de ba iye owo ounje laarin odun kan, gege bi ajo asewadi, iyen NBS, SE FIHAN, GEGE bi isoro atowoda.
ARAKUNRIN ADENIYI MOSES tun menuba bi ina apa ninu isakoso ile yi se n koba eto oro aje.
Awon oro yi atawon miran ni koko oro to jeyo lori eto Ǹ JẸ́ Ẹ TI GBỌ́ pẹ̀lú ANUOLUWAPO OGUNNIYI ati ADESEWA OSHO
E máa wo ikanni KAFTAN TV YORÙBÁ lori startimes decoder 132DT/482DTH
Негізгі бет ATOWODA NI ISORO OWONGOGO LORI OUNJE NI NAIJIRIA- ADENIYI MOSES
Пікірлер