O le ję pe won bę won ki won lo fun awón eniyàn wa ni majele ję nitori awón nkan ti o nşęlę yi o nfę amoju to o le ję pe won nfi ogun majele si sebi won ti ri pe ebi po ni ita awón eniyàn koni wo lę meji ki won to gbè ję iręsi ati agbado yęn onidi ifunrasi ni gidigidi sugbòn talo fę bere l'owo nwón, talo fę pe won lati şo pe nkàn ti won se ku dię Kato eleyi ti nwa d'oju ami bayi 😭😭😭😭 nkan buruku gbaa ni awón nkan wonyi ję
@Yasport2021
2 ай бұрын
We're getting there small small now.... Yoruba Nation no going back.
@estherewetuga8245
2 ай бұрын
Yoruba Nation no going back Yoruba Nation is the only Solution
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
Óró yi pa ni 😭😭😭😭 ni gidigidi ganni
@OlamilekanOmognolaha
2 ай бұрын
Yoruba nation most collect our glory back home ❤❤❤❤❤❤❤❤❤
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
This is the biggest slapped on our face but by God's grace everything we 🔜 be over and be a Tale by moon light The LORD will continue to strengthen abide and comfort everyone of us Ijmn Amiiin Amiiin Amiiin
@modupeolotu2918
2 ай бұрын
The governor of ondo state has cornered the monies for the palatives for his campaign funds, all these criminals politicians should be dealt with by the people before they will understand what up to their people. Awon oloriburuku omo ale dede omo iran kiran ni gbogbo awon politicians ile Yoruba and even none of them are even talking in the floor of their various chambers to speak on behalf of the their people, they are only going there for the looting of what belongs to the people.
@AjogunAdesokan
2 ай бұрын
The same thing for lagos
@olurantiosadare1873
2 ай бұрын
Yoruba nation know going back.
@francisoke1498
2 ай бұрын
why did he even brought it to his people. they could have went out there and start the protest straight off
@toyinorry4659
2 ай бұрын
THIS IS JUST TOO RIDICOULOUS WHY ARE THESE PPL SOO WICKED LIKE THIS?
@OmitogunDennis
2 ай бұрын
Ku ishe o! Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.
@sulaimantunrayo
2 ай бұрын
Yoruba nation is the only solution
@princetundeadebolu1210
2 ай бұрын
THIS IS A SHARE WICKEDNESS TO OUR BLESSED YORUBA LAND. IN THE NORTHERN PART OF NIGERIA THEY WERE GIVEN BAGS OF RICE, BAGS OF EVERYTHING. NIGERIA NEED TO DIVIDE
@emmanuelolusola534
2 ай бұрын
But the YORUBAS are satisfied with their oppressors. They said their people should not protest at all. I pity the YORUBAS, what's our problem gan an
@olatunji-n8p
2 ай бұрын
Yoruba nation is the only way out either they like it or not.(##just wait for it##).
@Joladeallison1351
2 ай бұрын
Absolutely NOTHING was given to the South West!!!. Awon South West Governors ti ya WERE! SA L'ARO!!!. NI GBOGBO WON!!!. Yoruba Nation lo le se! They can NEVER try this, when we get our own Country!!!. Won o bi won re!!!.
@florencedairo3888
2 ай бұрын
Se ko si bi awon enia wa se le le awon governor yi kuro ni office. Ki awon Omo Yoruba jade si ta ni millions ki woo gba ilu won lo awon governors ika yi. Eku e to o.
@oloriyeyeoge
2 ай бұрын
You’re very right!that’s our only way out! Talking,screaming,shouting will NOT achieve anything ! In fact we should start our own protest tomorrow ! We’ve got to come out in millions!the earlier th better FOR US ALL😭🤷♀️💔
@bashirumuhammedalliyu3533
2 ай бұрын
A o si aye wa a ko si shi ilu ya,were olori ni a ni.
@sulaimantunrayo
2 ай бұрын
Yoruba nation no going back
@FolasadeFagbola
2 ай бұрын
Gbadun lounloun kee? Won oni gbadun lagbara ooo
@Udonfęminukofo
2 ай бұрын
Ęku eto koleda jare my sis ❤
@yorubawuyitv1234
2 ай бұрын
Awon alaraka
@kehindeajasa2183
2 ай бұрын
Ayelagbe wuyi Abiola what a gorgeous, but you are adding more weight. Careful & watchful
@MaryOdunuyi
2 ай бұрын
Eyin eniyan wa, e ma so wipe won o fun South West, bakanna ni won se fun gbogbo won, awon ti wa ni olori OLE, won ni aanu loju rara, bi o ti wun ko ri. Ogun Orun lo ma kan gbogbo won mole, ni oruko Jesu. Amin. Yoruba Nation aa soju emi wa
@stephenbabalola3613
2 ай бұрын
Won sa kuro ni Aro!
@toyinorry4659
2 ай бұрын
ATIFA WERE LEPON😂
@yorubawuyitv1234
2 ай бұрын
Awon osinwin
@jemilaagbaje6238
2 ай бұрын
My sister, eku ise eku iyanju, kosiro nibe awon hausa ni anu arawon loju,toripe ile hausa lawagbe, sugbon Iran yoruba daju arawon gaaan ni
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
Iya mi o le ję won bu nkan le l'ori ki otà wa le di arindin ki won ma se ki a male şo nkankan ni nwón se fi ebi pa gbogbo wa sugbòn ADABI Abi gbogbo won adabi ęniti o ba se irè larin yin nikanşoşo lo malo irè ęni akoşi ba ęro adojutini ęda ikà odaju ędà 😭😭😭😭 o şo pęlu ibanuję okan ♥
@OlamilekanOmognolaha
2 ай бұрын
Oruko Koro gomina Ondo ofierugbaibunkunni Eledumarereeeee obaa yio Fi ayeniwonlaraaa lasetedumaree 😢😢😢😢😢😢😢😢😢
@AbosedeAdetola-x9e
2 ай бұрын
Wonma pada lewon lokopa nani
@yemisioladapo2011
2 ай бұрын
YORUBA NATION NO GOING BACK, SEPARATION IS THE SOLUTION
@jamesitaronbi3889
2 ай бұрын
Yorubawuyi ko si OLOSELU to lanu OMO ni ke ji RARA
@oregbesanmulikat8292
2 ай бұрын
Yoruba nation la fe
@bashirumuhammedalliyu3533
2 ай бұрын
Ejo ti gbe Owo mi😅😅😅
@MaryOdunuyi
2 ай бұрын
Ani ki e pa gbogbo won run pata parade lai ku eni kan
@AdeshinaSaheed-p7d
2 ай бұрын
Ibukun ni fun orilede yoruba ❤
@AdenijiBigMommy
2 ай бұрын
E kaasan ma, E ku Eto oooo
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
Yorubawuyi Gas ni won ma fill si ęhin Freeze abi Freezer eleyi ko funny rarà 😭😭😭😭
@AbosedeAdetola-x9e
2 ай бұрын
Akuku sayewa olori ilu lasiyan awon asiwajuwa wonmapada seleya ni
@yemisioladapo2011
2 ай бұрын
Honestly akoshi aye wa oloriburuku olori la shiyan
@fasuyiPelumi
2 ай бұрын
We Yoruba need freedom
@princetundeadebolu1210
2 ай бұрын
KPAI THE SOUTH WEST GOVERNORS, AND SOME YORUBA LEADERS NEED TO KPAI AND SOME OF OUR OBAS ALSO NEED TO KPAI IN THIS FORTH COMING PROTEST
@toyinorry4659
2 ай бұрын
KPAI KPAI NATION 😂
@victoriashittu6218
2 ай бұрын
Olorun Oba To Gba Awon Omo lsreal sile lowo Farao Agbeja WA pelu Anu Olorun
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
Boya agbado BILLGATE lati ilu UK 🇬🇧 ni yęn ę jowo ęnyin ęniyan mi ę ma ję Olodumare oke ati awón Alalę yio ma bo gbogbo wa a koni t'oro ję bi o ti wun ki o buru to ni gbogbo ibiti awa Omo Yoruba ba wa kakiri agbaiye Aşę Edumare Amin
@user-4234
2 ай бұрын
Oloselu South West ni o buruju ni Nigeria.
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
Ojo wo lafę se gbogbo eleyi da ganni 😭😭😭 ęnyin South West governor's ę koni ku irè rarà
@francisoke1498
2 ай бұрын
what an insult
@bashirumuhammedalliyu3533
2 ай бұрын
Se won le gbe fun Omo won ko je?
@yorubawuyitv1234
2 ай бұрын
werey ni won
@AdebisiMichael-b9k
2 ай бұрын
Sugbon awon oloselu S/W lo ya were ju eyiti ko sewo.
@bashirumuhammedalliyu3533
2 ай бұрын
Awon oloselu ti ya were mo olohun lowo
@AdenijiBigMommy
2 ай бұрын
A o si aye wa, ilu la si yan
@AbosedeAdetola-x9e
2 ай бұрын
Ekasan ma eku eto ooo
@oregbesanmulikat8292
2 ай бұрын
Same thing in lagos state
@yorubawuyitv1234
2 ай бұрын
ahhhh
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
Ę nsè ikà fun wa ę tub nfi han wa lojukoroju wa ęnyin South west gomina ę buru ganni ę koni ibęru Olorun boti wun ki o ri ę koni lo lai ję iyalaya iya t'omot'omo t'omo'mo t'idile t'idile yi bi Olorun ti mbę l'aiye 😭😭😭 ęnyin ako oşi ba ero😭😭😭
@AdebisiMichael-b9k
2 ай бұрын
Gbogbo awon Oloselu Ile Nigeria loni arun opolo.
@taiwobashorun1400
2 ай бұрын
Eeti mo nkan Kan.ole ni awon oloshelu Yoruba. Mo so tele wipe afi ti as ba pa gbogbo oloshelu southwest ki a to gbadun.
@omotosojosephine2271
2 ай бұрын
Oga ooooo
@SelimotaArike
2 ай бұрын
Olorun to da gbogbo wa yio gba esan iya ti won nfi nje gbogbo omo yoruba larawon
@demolaolamiposi2696
2 ай бұрын
A si ilu ya ni
@oregbesanmulikat8292
2 ай бұрын
Olori la siyo
@yorubawuyitv1234
2 ай бұрын
bęni o
@Sayitasebe
2 ай бұрын
Iresi majele
@boluwatipheoluwaferanmihab4427
2 ай бұрын
REDIONIC
@graceolushoto7115
2 ай бұрын
They wanted every indigenous people of Yoruba to die so that ours lands heritage culture and language will belong to Fulani and Biafra iyalaya iya ni gbogbo yin ati awón Omo nyin maję ninu aiye yi nkise ti ę ba ku
@jemilaagbaje6238
2 ай бұрын
Wonje iran kan tioni anu loju
@AbbeyKey-mh1lk
2 ай бұрын
😂😂😂😂😂😂😂😂😂
@demolaolamiposi2696
2 ай бұрын
😂😂😂
@francisoke1498
2 ай бұрын
that could be entitlement application fee😩😩😩😩😩😩😩😩😩😩😩😩😩😩😩😥😥😥😥😥😥😰😰😰😰😰😰😭😭😭😭😭😭
Пікірлер: 87