Thanks you for your advice and your advice to all of is the best and thanks you for that
@babatundekayode2019
4 ай бұрын
Yoruba nation no going back 💯
@ModupeKazeem-tp5ck
4 ай бұрын
Eku Eto kilode tiwonle Pari ija Larin Arawon. Ejowo Mofi Olorun Oba Asheyi Towun Oba ATERERE Karin Aye.Alapo Oshika.Epari Ijayin.Kaleni Ilosiwaju.Ifelakoja Ofin.Olohun Aranwa Lowo Min.Ni Ashe Edumare.❤❤❤
@hakeemlawal2429
4 ай бұрын
Omo Ogbon, opolo yin o ni d'oba.
@adesholabakare1490
4 ай бұрын
Amonran bini olote omo Yoruba ni e,
@dupebello3442
4 ай бұрын
Baba e ba won so ni Oyo pe ki won ma gbe omo fulani sori oye Alafin e ma nsoro ganni baba mi e bawa ba won so o ki won mafi fulani je Oba ni ile iwase orirun wa e bawa paruwo oro oye Alafin Olorun afun wa se o Amin
@adesholabakare1490
4 ай бұрын
Se gbogbo letter ti won fun gbogbo Nigeria government , eti e di sii yen
@mathewolusoladiekola1765
4 ай бұрын
Olorun ko ni pa laakaye yin
@adesholabakare1490
4 ай бұрын
Sebi iwon na ni onimona fiki ati awon aletenuje olote omo Yoruba
@safetydomain6861
4 ай бұрын
Baba mi Atiba Tvmo ki yin wipe eku ogbon. God bless you. Awa Yoruba nilo ati ati pe aro ati odofin inu wa, kale mo ibi ti a nlo. Lori oro Yoruba nation pelu letter lati odo baba Akintoye si are, ati esi awon Afenifere. Nina ore ofe Olorun, mo ni anfani lati ba omo egbe Afenifere soro, won je ko ye mi wipe Letti ti alokoro Afenifere ko sinu iwe ironing, awon Agbaagba ninu egbe Afenifere ko fi owo si, Koda won binu nitori oro naa, sugbon won kole pada sinu iwe iroyin latiso pe Afenifere ko so bee. Ife inu Alokoro egbe Afenifere lo se. Ninu atejade ti won gbe jade ninu egbe Afenifere, won so gbangba wipe awon ko lodi si Yoruba nation ti Professor Akintoye ati Sunday Igboho gbe dani. Won so wipe awon naa gba Yoruba nation gbo, sugbon won fe ki won Koko se atuto ofin Nigeria na, ki ole rorun lati jade kuro Nigeria patapata. We are applying different approach to get the same result but our people are not patient. There is nothing bad about the letter, since the same letter was sent to Buhari. It will not appear that it is only when a non-yoruba president is in power that we are threatening exit from Nigeria. Professor Akintoye is one of the elders council of Afenifere. All they need to do is have their strategies together and allow both ideas to run. Only God knows which one will come first. The secretary of Afenifere did not need to reply a letter that was sent to the president. The letter was not sent to Afenifere, and even if it was, the elders need to agree before he goes out there to publish a reply. I pray we will learn to work together to achieve a common goal even when our strategies are different.
@adesholabakare1490
4 ай бұрын
Eyin na ni onimona fiki omo Yoruba
@adesholabakare1490
4 ай бұрын
Iru yin na ni olote
@serahgibson5082
4 ай бұрын
GBENU E SOHUN,SE TINUBU TI DORI OYE, NIGBATI NWON NTI SORO, YORUBA NATION, IWO LOMA, TANI NRANMO NISE TORUTORU, SE AWON TI NSORO YORUBA NATION, SE NWON O KOWE SI BUHARI, AISE KI A MA RI OMOALE NI ORILEEDE, EMI GBADURA FUN O PE, ERU NI AWON OBI RE ATI IWO TIKALARA RE MASE KU. KIKIDA OMOALE GBOGBO.
@SalauSukurat
4 ай бұрын
Alabu yoruba ni iwon jumilo emi ju elo mo gba
@adesholabakare1490
4 ай бұрын
Democratic Republic of Yoruba New Nation ti bori , pelu agbara Olorun, efe e ko
@allstars6443
4 ай бұрын
Democratic of editing
@Bjponda1
4 ай бұрын
Atiba Oro lo so, ologbon ni Okunrin yi o
@gsjhsgshsusbbgshshshsjs5703
4 ай бұрын
Lati odun wo ni wontin bere fun atunyo opolo awon baba afenifere opolo won ti doba
@tayokokumo5260
4 ай бұрын
Gani will never agree. They must visit the court for Gani to stop all the fake rumors. Gani must learn a lesson.
@morohunfoluakinfosile4518
4 ай бұрын
God Almighty project. So please take note no power force nor any human can stop Yoruba Nation. It's already established by God Almighty.
@serahgibson5082
4 ай бұрын
YORUBA YIO SUCCEED NI AGBARA OLORUN OBA, GBOGBO ONI MONAFIKI NI KONI GBERI, NI ILE KOOTU-OJIRE, KODA KOYO GBOGBO WA, ATI EMI TI MO NBA NYIN SORO, GBOGBO WA PATA NI AO JERE ISE OWO WA NI ILE KOOTU-OJIRE, TORINA KOSI ENITI KONI JERE ISE OWO RE, KI O TO JADE LAIYE.
@kehindeoyetunji1686
4 ай бұрын
Afenifere are fighting for their personal interest bcos vice-president Shettima said nothing like restructuring, restructuring my foot, to hell with the restructuring. Why Afenifere stands in the wrong direction .Yoruba is the main BIG problem of Nigeria as a whole
@jameslincoln2796
4 ай бұрын
AFENIFEBI they have been asking for RESTRUCTURING for the last 40 years. MATIU 10 :36 ARA ILE ENIYAN NI YOO SI MAA SE OTA. They are enemy within for the YORUBA. YORUBA NI OTA YORUBA
@deboraholorundipe2706
4 ай бұрын
It is round table they are calling for. That is the motive of the letter. People are just misunderstanding them.
@AderakinyoComfortIyabo-rh6or
4 ай бұрын
Who is abiola
@idrisadigun1381
4 ай бұрын
always baba ogbon
@abetoba2331
4 ай бұрын
Eku eto, kilode ti e kofun baba Akintoye ni imonran lati igbati wonti fi letter ranse SI buari ? Imonran ki seti enikan
@jameslincoln2796
4 ай бұрын
It's the fundamental right of indigenous people to reclaim their NATION back to ORIGINALITY as a NATION. The right of indigenous people to self DETERMINATION is under united nations rules not ABDULSALAMI FRAUDULENT DOCUMENTS CALLED CONSTITUTION. DEMOCRATIC REPUBLIC OF YORUBA HAS COME TO STAY. Nobody knows that DAVID will killed Goliath
@adesholabakare1490
4 ай бұрын
Olodo , sebi eyin ti IQ lo na le n fa wala ile Yoruba , ati fiditi ati gbogbo yin ori yin ope
@user-ig6zg4zp4p
4 ай бұрын
E woo modupe lowo yin ,o ye ki baba wa Banji Akintoye na fiwesowo si gbogbo awon oba wa pata ati gbogbo awon Afenifere fun lpade alafia pellu Are wa papa ,SE ri nkan ti loye lgboho so ni PE ,ki a Koko Le awon Fulani lo na , SE ri eye to nlo kakiri PE ,kiisasiko Yi ni o ye kabere Yoruba Nation nooo awareness LA nso Nipa re Yi. Sugbon bi lmonran temi nope ,ki baba asiwaju to pari Odun merin akoko Yi, KI YORUBA PE ARA WON SI RAND TABLE BI EMEJI EMETA .WO IWOYE MI NI PE KI BABA WA TINUBU MA LERO PE AWON FULANI YI MA FAYE EMEJI SILE O . KI YORUBA MA SE MISSTAKE IRU E RARA .( BI ODUN KERIN AKOKO BA TI FE TENUBEPO ,KI AARE PE FUN PINPIN KI YORUBA MA SORAE SINU OKUNKUN AYERAYE ,IJAFARA LEWU .KI CSI MA SEJO MON ,NKABI IMORA TI MO KO SINU COMMENT MI KI ORO TO DE COURT NI PE ,KI AWON OBA WA PE BABA WA GANI ADAMS ATI OLOYE BABA WA SUNDAY PO KI WON PARI OROYI FUN KIN ,KI WON SE IBURA FUN WONPE ENIKINI KO BGODO PERI ENIKEJ .E JOWO SA E NI KA MA COMMENT AWON COMMENT KIIJE AMUNSE ,TA BA RI IMONRAN TO DARA O YE KALE PERU ENIBE LORI PHONE SUGBO KO SELE RI
@jameslincoln2796
4 ай бұрын
Akintole and Sunday DAGBORU YORUBA NATION IN THE MORNING TINUBU APC IN THE NIGHT. AJA OLE SO OJU LE MEJI. THE SADDEST THING ABOUT BETRAYAL IS THAT IT NEVER COMES FROM YOUR ENEMIES. Mr Akintole and Sunday DAGBORU are enemy within for the YORUBA
Пікірлер: 42