Latest Yoruba Song and Movie *winks from Bisimanuel and Heeyarhnu
Eyin Oba Ogo, On ni Olorun (Hymns) - Latest Yoruba 2022 Movie and Song
Eyin Oba ogo, On ni Olorun
Yin fun 'se 'yanu ti o ti fihan
O wa pelu awon ero mimo l'ona
O si je imole won l'osan l'oru.
E yin Angel 'didan, lu duru wura
Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re
Ni gbogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo
Ise re y'o ma yin
Ise re y'o ma yin
Fi ibukun fun Oluwa okan mi.
Powerful Lyrics, Powerful Words, Enjoy.
#latestnews #yorubamovies #bisimanuel
Негізгі бет Eyin Oba Ogo, On ni Olorun (Hymns) - Latest Yoruba 2022 Movie and Song | Bisimanuel and Heeyarhnu
Пікірлер: 44