Asiri tu lasan ni,sugbon kosi igbese lati fi iya je awon Oloselu Ole akotileta yi .Olorun loma fiya je gbogbo won
@mariamasie9329
6 ай бұрын
Ole gbe ole gba.
@sakenatafolabi8666
6 ай бұрын
Awon OLEEEEE gbogbo oloun a mun yin pa.E rare kan ni tomo tomo Amin 🙏🙏🙏...........BABA WA TINUNBO OLOUN A fUN NI AUNFANI LATI BAWA TUN NIGERIA SE O ABO OLOUN TOPEYE A MA WA PELU YIN AMIN KUNFAYAKUN 🙏🙏🙏❤❤❤❤❤❤❤
@odunolaalli6773
6 ай бұрын
Emefele ti run gbogbo Oro aje Nigeria, Ori mekunu ko ni je ko dara fun o loruko jesu
@adewaleadeniran2534
6 ай бұрын
Gbogbo e lo nii esan oluwa a gba awa mekunu lowo yin ooooo
@adecrown4413
6 ай бұрын
Alaroye, alaroka.olote oju yin ti wale? Alaroye ole.
@dotunosa
5 ай бұрын
But this people's don't think that. They're going to die and leave this behind. Lord have mercy
@ogunrindeadebisi
6 ай бұрын
Olori Awon odaaran , Oloriburuku OLEE NLAA, Gbogbo awon TI Emi wan bo SI WAHALAA change of Money in 2023 Jan till March , Okuu wanyen majeki EMEFIELE toroje gbeyin Aye E Tomotomo , EMEFIELE màraare KUU NIOOOO niagbaraa Olorun Amin 🙏 , Baba Jagaban Nigeria President Thank U Sir for the Good Job.
@sakenatafolabi8666
6 ай бұрын
Amin kunfayakun 🙏
@gafaradeyinka
6 ай бұрын
Amin
@princessrobinson2846
6 ай бұрын
😮😮😮😢😢Ẹ̀rù Ọlọ́run alààyè bà,mí o. Mo bẹ̀rù àwọn olóṣèlú orílẹ̀ èdè Nigeria o. Ọlọ́run jàre gbà, wá lọ́wọ́ àwọn ọmọ aráyé. Àwọn olubi ènìyàn. Àwọn aṣebi, aṣeni báni dárò. Aṣekúpani ,aṣeni,tán bani,dárò😢😢😢. Aláròyé ,ẹ ṣeun lọpọlọpọ gaan ni. Ẹ̀yin lẹ, o jẹ́kí etí wa di. Ẹ kú iṣẹ́ ọpọlọ àti akitiyan ní gbogbo ìgbà ❤❤❤❤❤
@scrypa3010
6 ай бұрын
Aminnnnnn oloriburuku emefiele, oni jere aiye pelu awon mewa e
@tayelolugbenga1898
6 ай бұрын
Iku gbigbona lo maa pa emefiele. Ase!!!
@bodew4836
6 ай бұрын
emefiele ati gbogbo awon oloribburuku ti won jo se ijoba Buhari ti je naija run o
@alaosunday9274
6 ай бұрын
Hahaa enikan soso banki merin!!!
@Adegoroye3am
6 ай бұрын
Criminals of the highest level
@user-fp1pz2gg8x
6 ай бұрын
AMIN AMIN AMIN OOO
@kaberemuretv8919
6 ай бұрын
Amin
@wosilatamosu9017
6 ай бұрын
Emefiele VOLEUR OLÉ THIEF OLEEEEEE😮
@jonhsonakinbule3511
6 ай бұрын
Ekuse iwadi kodoro lori Emeifiole
@giveway...6838
6 ай бұрын
AmiiiiiiiiiiN Ni Oruko Jesu Kristi 🙏
@rufaitaofik8995
6 ай бұрын
The truth is out of 1,000% Nigerian's properties the government just received only 1% from efewelemeweleoleee😂😂😂
@user-fp1pz2gg8x
6 ай бұрын
ALAROYE HI LOVE ❤️ YOU SO MUCH
@OlowoleSunday-xg1gv
6 ай бұрын
Haaa😮 emefele
@ajegunmowasiu3948
6 ай бұрын
Emefiele ole nla
@oyewole5530
6 ай бұрын
Very comprehensive and serious revelation of fraud and irregularities compiled by Alaroye weldone and respect to Alaroye
@lukmanagbagbe631
6 ай бұрын
Hmmmmmmm Nigeria Ole gbe ole gba
@basiruabiola2835
6 ай бұрын
Oponu gidi ni e
@adeyemiyusuff6458
6 ай бұрын
Amen oooooooo OLOHUN
@Alhaja_omosalewa
6 ай бұрын
Allahumo amin
@mustaphaalibagu2662
6 ай бұрын
Se loye ki wan di emefiele ma agba
@niewagen7376
6 ай бұрын
Dead corpse in Aso Rock for 8 years
@mustaphaodeshina5111
6 ай бұрын
Ọmọ Igbo. !!! ole
@timothywale8055
6 ай бұрын
Odabi wipe ero okan mi ti fe ma yipada si president wa yii o , se wipe Tinubu le maa sise ribiribi bayi ? Se eniti aro wipe kole pagoo ,le ma kole alarinrin bayi ? Adura mi ni wipe ki awon elemi esu miran mase kosi Tinubu ninu bii ti Buhari o ,kii Tinubu le se aseyori Amin
@JhonePellon-gx7pk
6 ай бұрын
Hmmmm Ibiti o ti yeki bola hamed ko awon soja loja won ko won lo Abi Se eo ri ija buruku ti won ja ni ipinle kwara ni ? Hmmmm Abi ibiti won tiso pe ki won ma sprayed ibon lo ni ojosi nko Lekki 1st gate laye endsars Hmmmmm E wa ngba banki lowo emefele ? O ga o Won paayan lo ni kwara eyin ngba banki Eyin teba gbon e tete yaa mon bi eo se / se aabo Lori ara yin Ao ko Mon ni alaabo ni nigeria
@adewaleadeniran2534
6 ай бұрын
Gbogbo e lo nii esan oluwa a gba awa mekunu lowo yin ooooo
@adewaleadeniran2534
6 ай бұрын
Gbogbo e lo nii esan oluwa a gba awa mekunu lowo yin ooooo
@adewaleadeniran2534
6 ай бұрын
Gbogbo e lo nii esan oluwa a gba awa mekunu lowo yin ooooo
Пікірлер: 42