Onigbagbo Ki i jade lai juba o
Iba Iba Iba Iba Jesu O
Onigbagbo Ki i jade lai juba o
Iba Iba Iba Iba Jesu O
A kii juba olorun ajeji o
A kii juba olorun ajeji o
Oluwa oluwau wa wa
Oruko re ti niyin to
Ah jowo foriji wa
Ah jowo foriji wa
Jowo foriji wa o oluwa
Jowo foriji wa o
Emi orun jowo wa, olugbala oba jowo o
Jeki emi re baba iye
Ko wo ba sori wa gbogbo
Iwa eeri wa gbogbo
Jowo foriji wa o
Jowo foriji wa o oluwa
Jowo foriji wa o
Iwa eeri wa gbogbo
Jowo foriji wa o
Emi orun jowo wa, olupese oba jowo o
Jeki ibujun re baba iye
Ko wo ba sori wa gbogbo
Iwa eeri wa gbogbo
Jowo foriji wa o
Jowo foriji wa o oluwa
Jowo foriji wa o
Iwa eeri wa gbogbo
Jowo foriji wa o
Негізгі бет Музыка Iwa Eeri Wa Gbogbo Jowo Foriji wa
Пікірлер