THANK YOU ABBASS LAJI..THANK YOU SIR I LOVE YOU SIR FOR THIS GOOD JOB YOU ARE DOING.
@MikhailAwolowo-zm7fr
2 ай бұрын
A dupe fun Olohun ti o fun awa omo kuootu oojire ni aseyori ti oni. Eleyi yo je ate gun ilosiwaju awa omo Yoruba. Awon eniyan lori ile aye, ti ojulowo itan won ba pare, ti di eni anu, ti won ko ni jamo nkankan mo.
@ayinlamedia1832
2 ай бұрын
It was a great experience and very educative
@leahayodele2526
2 ай бұрын
ONIBODE ITAN YORUBA LAND. EKU ETO NAN YORUBA KONI PARA MAIYE ..YORUBA PEOPLE EKU ORIRE BE NI AO MA SE TITI LAYE.
@empresskofoworola
2 ай бұрын
Are Opita eku orire 🙏
@jeylamix6695
2 ай бұрын
Eku orire
@Majority33
2 ай бұрын
Adupe lowo Olodumare fun aseyori ètò naa.
@gbemisola9886
2 ай бұрын
A dupe lowo yin fun ilana eto ti e gbe kale yii. Olorun a tunbo fun yin se, aduro ti yin, Olorun a se atileyin yin ati gbogbo a wa omo ijinle Yoruba.
@kehindeandu4040
2 ай бұрын
E ku oriire na Oluko Agba !!! Ire ati anu Olorun yio ma ba yin gbe o. ❤
@oyeyemisosanwo7646
2 ай бұрын
Aku aṣe yọri ti oni, Aarẹ Laji Abass
@azeezkamarudeen8465
2 ай бұрын
Baba mi Laji Abass ki olodumare bawa lora emi yin fun....eyin ni emi itan Yoruba ni asiko Tia wayi
Пікірлер: 15