I connect myself and family to this mountain prayer amen
@loladeoyebade9184
Ай бұрын
I connect myself my entire household with the mountain in the name of Jesus
@OluAkitoye-gt2or
Ай бұрын
I connect myself and my family to these prayers
@mosunkuku5391
Ай бұрын
I connect myself my children and my grandchildren to dis prayers
@Doyinzanna
Ай бұрын
I connect my spirit with the spirit of the men of God in this mountain ⛰️ prayer, I received answers to all my prayers in Jesus name 🙏
@mojisolaraji8628
Ай бұрын
Amin ni oruko Jesu pe modupe ti mo se alabapi ore-ofe ori-oke yi gbogbo adura na mo gba tomotomo pelu igbagbo Majemu Anu ni oruko Jesu amin
@AdesunkanmiEbunlomo
Ай бұрын
I connect My family with the mountain prayers in Jesus name with baba TaiwoOjo
@user-fc6rk7jn7e
Ай бұрын
Thank you, Jesus.
@tojuadeayoola1209
Ай бұрын
Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin loruko jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Oluwa gbe mi dide, eyi ti mo se loju kan o to gee, Oluwa gbe mi dide, orun gbe mi dide tomotomo, iya ojukan yi to gee, Emi Mimo gbe mi dide tomotomo, gbe aye mi dide, gbe awon omo mi dide, aanu gbe wa dide loni loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Gbogbo ala ibi, iran ibi, asotele ibi ninu aye emi ati awon omo mi, Oluwa fi aanu yi won danu, ogun alakala, ogun irankiran Oluwa ma je ko bori mi, ma je ko bori awon omo mi, Oluwa gbe mi bori ala ati iran odi ninu aye mi ati awon omo loruko Jesu
@aduniadenekan183
Ай бұрын
I connect myself my children my husband and my all my brothers and sisters to this prayer line IJN Amen!🙏🏽🙏🏽🙏🏽🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥
@mosunkuku5391
Ай бұрын
Thank you Jesus
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Oluwa nitori pe mo se alabapade ori oke yi, fi aanu gbe mi dide tomtomo, gbogbo asotele ibi ati okunkun ninu aye emi ati awon omo mi, ina Oluwa gbe won mi loni loruko Jesu, Oluwa da eyonu ati aanu re lu mi tomotomo, la ona abayo fun mi ati awon omo mi, je ki n ba ojurere eniyan ati ti Olorun pade, Olorun iranlowo jade si mi, pelu mi tomtomo lati oni lo loruko Jesu
@user-jj5ug3dc5y
Ай бұрын
Thank you Jesus for everything
@olabodeesthertaye3524
Ай бұрын
Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen in Jesus name. 🔥
@aduniadenekan183
Ай бұрын
Daddy may God Almighty continue to strengthen you and everyone IJN Amen. 🙏🏽🙏🏽🙏🏽🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥
@victoriasalako5402
Ай бұрын
AAALLLL GLOOORRYYYY Honour Adoration Exaltation THANKSss & PRAISESss To Our Wonderful Perfect Gorgeous Faithful KIND JEHOVAH ALMIGHTY FATHER GOD. UnLimited ReSounding HAAALEEELUUUYAAA!
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Ni oruko Jeeesu, Emi mimo, gbogbo majemu itopinpin to n monitor aye mi ati awon omo mi, Oluwa ba won je lori oke loni, agbara atopinpin to n monitor ogo mi ati awon omo mi, Oluwa ba je loni, fo oju atopinpin lara emi ati awon omo mi loni loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Ni oruko Jeesu, okan mi n fe owo nla lati fi yanju bukata to wa niwaju mi, mo n fe aanu nla fun awon omo mi, mo oore-ofe lodo Olorun ati eniyan, mo fe ojurere Olorun lori aye emi ati awon omo mi, mo fe igbedide ati ogo tuntun fun awon omo mi, Oluwa fi aanu yi wa ka, tan imole si ona aye emi ati awon omo mi loruko Jesu
@maryonasanya4874
Ай бұрын
Amen amen amen fire fire fire
@monisolaadebowale1938
Ай бұрын
I connect myself and all my children to this prayers of the mountain lJN
@amusanidiat504
Ай бұрын
Amiiiiiiiiiiiiin, Amiiiiiiiiiiiiin, Amiiiiiiiiiiiiin, Amiiiiiiiiiiiiin, Amiiiiiiiiiiiiin, Amiiiiiiiiiiiiin, Amiiiiiiiiiiiiin loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Gbogbo ero okan mi ati ohun rere gbogbo ti mo n beere fun mi ati awon omo mi, Olorun fi aanu yonda re fun mi, igbega ati ilosiwaju, ojurere ati ibi giga ti mo nfe fun awon omo mi, Oluwa fi aanu yonda re fun mi, saanu aye mi, gbe mi dide, pese fun iranlowo, dari alaanu ati oloore ti kii su, ti kii re si mi tomotomo loruko Jesu
@christiana1037
Ай бұрын
Lord you're Mighty and Powerful. I salute you SIR.
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Ase ti aye fi dami duro, Oluwa fi ase orun gbe mi, gbogbo ase ti aye fi da awon omo mi duro, Oluwa fi ase orun gbe won, Oluwa fi ASE gbe ase aye mi lori mi ati awon omo mi, fi ase ina gbe ase aye mi lori mi ati awon omo mi loruko Jesu
@amusanidiat504
Ай бұрын
Loruko Jesu, agbara ti ko se daduro gbewo KISTOMEADIFSKSMYSPMAAEVAGMAHLLDD loruko Jesu.
Gbogbo emi ko seese ninu aye emi ati awon omo mi, mo pase fun o jade, ki o lo gbe danu, emi ko seese ati aseti, ninu aye emi ati awon omo mi ba ina jade loni loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Gbogbo ohun to n be ninu aye mi ti ota fi n ni mi lara, Oluwa fi owo ina gbe jade, gbogbo ohun ti ota toju si mi lara, to n ni aye mi lara, gbogbo ota toju si awon omo mi to ni aye won lara, Oluwa fi ina gbe won jade, Jesu fi owo ina Nla re gbe won jade ninu aye wa, ki aye emi ati awon omo gba isinmi,
@amusanidiat504
Ай бұрын
Amiiiiiiiiiiiiin loruko Jesu tomotomo, tomoomo, tokotoko, tokotaya omo loruko Jesu.
@amusanidiat504
Ай бұрын
Amiiiiiiiiiiiiin loruko Jesu tomotomo loruko Jesu
@alicedayo8542
Ай бұрын
Amin ooooooo Jesu kristi
@christiana1037
Ай бұрын
Amin Amin ati Amin ni oruko Jesuuuuuuu
@amusanidiat504
Ай бұрын
Baba womi mi agbara tomotomo, tomoomo, tokotoko, tokotaya omo, ki a ma ba waye asan,wo wa ni agbara loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Oluwa wo mi agbara tomotomo ki emi ma baa wa asan, ro mi lagbara ki n ma se wa ofo tomotomo, Jesu wo mi lagbara
@folashadelaboarde6780
Ай бұрын
Gbogbo alabagbe to npetepero ibi lorimer ati omo ati omomo ko fi owo ara wo se ara won amin amin loruko Jesu amin
@thomasjohn-dz1yz
Ай бұрын
amen
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Amin Jeeesu
@amusanidiat504
Ай бұрын
Mo gba tomotomo ohun rere ti okan wa n pongbe fun loruko Jesu.
@ayomililly6037
Ай бұрын
Amin loruko jesus
@maryonasanya4874
Ай бұрын
Amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen
@gracesowunmi4838
Ай бұрын
OLUWA ESE FUN ORE TI EMI ATI AWON OMO MI RI GBA NINU ADURA YI JESU ESE OOOOOO MORE ANOITHING IN JESUS CHRIST NAME SIR
@amusanidiat504
Ай бұрын
Amiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiin loruko Jesu
@amusanidiat504
Ай бұрын
Amin loruko Jesu
@OluAkitoye-gt2or
Ай бұрын
Please God send me elpersinn Jesus name iam always helping there please send helpers to me
@DavidUmukoro-uu7pw
Ай бұрын
Amin Amin Jesu
@amusanidiat504
Ай бұрын
Amiiiiiiiiiiiiin loruko Jesu
@christiana1037
Ай бұрын
Aminooooooo Jesu
@user-jj5ug3dc5y
Ай бұрын
Hallelujah x7
@HURPSYYEMRAY1
Ай бұрын
🙏🏻🙏🏻🙏🏻🙏🏻🙏🏻
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Ami to wa lara mi ati awon omo mi to n tako ire, eje Jesu pare, eje Jesu we danu, gbogbo ami to n tako ire ati aanu, to n tako igbega, to ntako ojurere ati oore ofe ninu aye emi ati awon omo mi, eje Jesu pare loni
@Mission4ChristMedia
Ай бұрын
Olorun Taiwo Ojo bami baje loruko jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Gbogbo iran odi ati ala odi lori aye mi ati awon omo mi, Oluwa ba mi ba gbe ki adura yi to pari Oluwa ba won, ala odi, iran odi, asotele odi lori aye emi ati awon omo mi, Oluwa ba mi ba won je
@adelekefolasade6308
Ай бұрын
Gbogbo oro ASE odi taye fi da mi duro Olorun ASE oro fase gbe mi
@christiana1037
Ай бұрын
Amen Amen and Amen in Jesus name
@christiana1037
Ай бұрын
Amin Jesu Amin Jesu Amin Jesu Amin Jesu Amin Jesu Amin Jesu Amin Jesu
@christiana1037
Ай бұрын
Amin Jesu
@yodedina
Ай бұрын
Amin Jésù
@amusanidiat504
Ай бұрын
Halleluyah loruko Jesu.
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Ni oruko Jeeesu, gbogbo agaja ami ti mo n ri loju oorun ati ala to maa n fa idena, to maa nfa ijakule ninu aye mi ati awon omo mi, Oluwa fi eje re pare, agaja ti mo n ri nigba ti aseyori ba ti sun mo mi, Oluwa fi eje re pare, lori aye awon omo mi, Oluwa fi eje re pare, agaja idena, agaja ojukan ati ijakule ninu aye emi ati awon omo mi, Oluwa fi eje re pare loni loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Ni oruko Jeeesu, gbogbo owo to n da mi duro, ki adura yi to pari, Oluwa je ko gbe danu, gbogbo owo to n da awon omo mi duro, to n da ogo awon omo mi duro, Oluwa je ko gbe danu, ati owo ati olowo, Oluwa je ki won gbe danu loruko Jesu, owo idaduro ninu aye emi ati awon omo mi, o ya gbe danu, owo idaduro maa gbe loni loruko Jesu
Olorun orike yi gbo adura mi Olorun Taiwo Ojo oseun oooo
@amusanidiat504
Ай бұрын
Halleluyah
@user-jj5ug3dc5y
Ай бұрын
Daddy e ku ise oluwa akotun agbara loruku Jesu krist
@mojisolaraji8628
Ай бұрын
Praise God I connect myself children in-laws grdchildren and Bamidele and Adedayo today's ALTAR of mountain service with the anointed Man of God more anointing Spiritually strength upon you in Jesus name amen and I make a request for myself growth in Spiritually and PHYSICALLY my losses to be returned in Jesus name amen and good health.
@moyinoluwaadegbehin6665
Ай бұрын
Thank you Lord
@folashadelaboarde6780
Ай бұрын
Abinibi to Pete ati pa aware ko ku iku to nbere fun loruko Jesu amin amin amin loruko Jesu amin
@teniolayusuf3828
Ай бұрын
God bless me and everybody
@tojuadeayoola1209
Ай бұрын
Oluwa fi Anu gbe mi dide tomotomo
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Oluwa seun, ogo ni fun Jesu loke orun
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Halleluyaaaaah
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Halleluyaaaa
@mosunkuku5391
Ай бұрын
Amiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiin Jeeesu
@amusanidiat504
Ай бұрын
Loruko Jesu gbogbo ohun ti aye gbe si KISTOMEADIFSKSMYSPMAAEVAGMAHLLDDSAKILAYIAYOM LARA,TO N NI WA LARA TI WON DA IGBA ATI AKOKO FUN,Olorun majemu anu gbeeee jadeeee loruko Jesu
@user-ki9qf3rx1q
Ай бұрын
Jesu e se tire logo tire lola tire ni iyin Jesu e se ganni
Oluwa mo dupe wipe mo rire gba loni, wipe awon omo mi ti aanu to ojo oni gba loruko Jesu
@bilikisubolajokoamoje2707
Ай бұрын
KAAABIYESI KAAABIYESI ooo ELEDUMARE OBA AFIIYIN SEGUN
@mojisolaraji8628
Ай бұрын
Oluwa wo mi ni agbara ki emi ma ba wa aiye lasan
@AkindoyeRotimi
Ай бұрын
Àmin
@amusanidiat504
Ай бұрын
Oluwa modupe, e se o.
@amusanidiat504
Ай бұрын
AMIIIIIIIIIIIIIN LORUKO JESU
@bilikisubolajokoamoje2707
Ай бұрын
OORE JESU ni
@amusanidiat504
Ай бұрын
Iwo emi kosese ninu aye KISTOMEADIFSKSMYSPMAAEVAG MAHLLDDSAKIOLAYAYOM jade loruko Jesu.
@amusanidiat504
Ай бұрын
AMIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIN, AMIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIN, AMIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIN, AMIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIN, AMIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIN, AMIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIN LORUKO JESU
@amusanidiat504
Ай бұрын
Ami wo lo n be ara KISTOMEADIFSKSMYSPMAAEVAGMAHLLDDSAKILAYIAYOM to ntako ire,Jesu fi eje re pare.
@ayomililly6037
Ай бұрын
Ogo folorun loke orun
@amusanidiat504
Ай бұрын
Oluwa dariji mi,nitori aanu re,.
@adeyemiileaje4238
Ай бұрын
Oluwa fi ase la ona fun mi, gbogbo ona to ti di, Oluwa fi ase la, ona to ti di mo mi ati awon omo mi, Oluwa fi ase laa, la ona irorun fun mi ati awon omo mi, la ona igbega ati igbedide fun mi ati awon omo mi fi ase agbara re la gbogbo ona ti aye ti di mo emi ati awon omo mi loruko Jesu
Пікірлер: 107