ti awon oba yi ba ni problem awon omo yoruba ma n dide ti omo yoruba ba ni problem oba kankan kin dide let them face there's problem because all this king's doesn't care for yoruba problem
@adeagboaremu1019
10 ай бұрын
Orí-Adé kìí sùn ‘ta; Èyi kìí sé pé Oba kìí sun (sleep) ní ìta. Ìtumò rè ni wípé; Bí Oba bá wàjà ní èhìn-odi, ó di dandan kí a gbé E wá sí ibiti won ń sin àwon Oba sí. Àwon Oba a máa sůn (sleep) ni òde.
@badmos6966
10 ай бұрын
Yatosi pe boya Alaroye ka iroyin eleje Oriade koriade toba si agbara lo a losi ewon monakai.
@comfortadeleye128
10 ай бұрын
OODUA AGBE YIN EKU ISE TAKUNTAKUN
@olorioritokesalami1452
10 ай бұрын
O ye ki won sue ile ise alaroye ni
@jeylamix6695
4 ай бұрын
Kabiesi gan ko gbo ede Yoruba yanju, o ma se o
@mayowaidowu7081
10 ай бұрын
There is another Oko in Kwara State, beside Omuaran, are they related?
@deedotist
10 ай бұрын
When DISPLINE is dead in an environment 😢
@kehindejosephkashimawo9410
10 ай бұрын
Àgọ́-Òkò wá ní Abẹ́òkúta.. Ibe ni Olú ìlú Ẹ̀gbá Òkè-Ọnà tí Ààfin Ọṣilẹ̀ Òkè-Ọnà wà láti aiyébaiyé.. ..
@kehindejosephkashimawo9410
10 ай бұрын
Alaroye fẹ́ bá ilẹ̀ Yorùbá jẹ́.. Wọ́n ngbé Iroyin ẹlẹ́jẹ̀..Lori Ọba ìṣẹ̀mbziyé ilẹ̀ Yorùbá, Ọba Ìlú Òkò Ọ̀ranmíyàn
@comfortadeleye128
10 ай бұрын
But why ALAROYE of all papers they should have do diligence to make enquiry before publishing such a news
@olaideogunjobi2608
10 ай бұрын
Oko muke , idi e muke, omo ajigbe sobolo gunmo ni'tan. Mo ra pakiti ogofa lo'ko, ojo kefa logbo tuutu, nibi mogbe n sunkun oorun.
Пікірлер: 14