Yoruba ni,Airin jinan lai rabuke Okere, agbara po repete ti Oba Oke da. ibi ti aba rin de la o mon de. iwadi wa pelu agba ode yi fi asiri lorisi risi han wa
- Күн бұрын
Ogboju Ode: Awon Iwin lo nko wa logun ti won nfun awa Ode lagbara. Ologbo ni iwulo to po repete
- Рет қаралды 20,106
Пікірлер: 34