Ogo nifun Oluwa wa ni oke orun fun ipe ti Oluwa peyin lati tusile ati lati gbala Oluwa si ndabira nitori majemu ni eyi, asi nri owo iyanu Oluwa, botile jewipe ako riyin soju Sugbon Oluwa ndabira ninu ayewa Ogo Ogo Ogo ni fun Oluwa Halleluya aku isimi akoko ninu OSU kejila emi ni kan
Пікірлер: 8