Thank you... history of our king refreshing and enlightening... Oyo mojuba o.
@kehindejosephkashimawo9410
3 жыл бұрын
Gbenga Adebayo Oladunni tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí: "Imalian boy" ni ẹni tí ó kọ orin tí ẹ fi ṣí 'de ètò yìí: "yiye ni ń yẹ ẹiyẹlé".. Agb'óhun s'afẹ́fẹ́ ni, ni OGBC Abẹ́òkúta. Ó sì tún jẹ́ akéwì, òǹkọrin àti eléré orí ìtàgé..Ará ìlú Ìmálà ni Yewa ni. Tori ré ló ṣe pe ara rẹ̀ ni: "Imalian Boy".
@fausatbello1196
4 жыл бұрын
Oluko agba e ku ise ooo,ejowo nigbati Ashipa je oju Oba,kiwalofa ija laarin Oba Adeyemi 3.atipe kilode ti won kofije Ashipa mo nilu Oyo ati pe kilomuwon ko oye Ashipa yi lo si ile Daodu nisale Oyo eseee ooo amariyin baooo ti Ilekun Ashipa si di titipa di onioloni
Пікірлер: 7