OLORI BURUKU NI GBOGBO WON NIGBA TI WON UNPA LOGUN LOGUN LOGBON LOGBON NIBO NI AWỌN TÍ GBIJA OLORUN YI WA KI SUNDAY IGBOHO OSHA OWO BABA DAMI TO JADE EMADA WỌN LOUN AWỌN OTA ILE YORUBA NATION NI YE YORUBA NATION NO GOING BACK 🎉🎉🎉❤❤❤
@omoyelesamson2150
5 сағат бұрын
Sunday Adeyemo Igboho kotile gba ki won fi oun we Anobi tabi Jesu o
@okeadetola8231
4 сағат бұрын
God bless you and the alfa also right by saying igboho should come out and debunk but this idiot taloloun was most idiot ever
@JimohTijani01
5 сағат бұрын
Yoruba nation no going back
@silifatonagun1750
6 сағат бұрын
Eyin Alfa, ejowo tori Olohun emun oju kuro nipa ti Oloye Igboho, oro ko kan Oloye Igboho rara, toripe Igboho ko bawon lowo si ija esin rara, Igboho ki se eniyan beyen, Igboho kiyaju si enikeni katowa sope oma so isokuso si ojise Olohun
@aregbesoladaniel2383
6 сағат бұрын
Who's Anabi ni ede Yoruba? Sebi wolii lo nje bee, se enikan lo nje wolii ni? Ija esin le nkowe si,sebi arayin loso pe ole ni JESU pe o ji agbado alagbado etunni o ji ketekete-oniketekete, e joo iya tio nje Omo Yoruba ti to e maje ki atun ba ara wa jija esin God bless you, Yoruba nation no going back
@GBADEBOGBADEGESIN22
7 сағат бұрын
Eyin Alfa oni gele lori ilu Ilorin ẹ lọ joko jee Igboho Oosa ki ṣe alarinfin fun anyone
@ruthjolaoso9872
7 сағат бұрын
Asake weldone
@ruthjolaoso9872
7 сағат бұрын
Chief Dr. Sunday Igboho Ooosha o ni jade nitori o un ko lo soro
@92olamiArabMoney
6 сағат бұрын
Awon Oni jagidijagan Eda
@FataiAbimbola
5 сағат бұрын
Awon Oponu ayirada, elo wa ibi kan joko si. E ko ara yin gba Saudi. Ina lenpe sorii yin apaniyan ni lati wo ina, E yipada ki ibinu Olorun to baa yin. ❤❤❤❤❤❤ 😂😂😂😂😂😂
@ABDULKARIMSALMAN-d5m
7 сағат бұрын
Eyin Yoruba e fura,E ma gba esu laye ooo,E ma da ija esin sile ni ile Yoruba,ko ni so ESO rere,, Ohun ti e fi sere yi to ba be sile yio ta bale ta ba oko,
@KaptainZulu
6 сағат бұрын
Ko sì n'kan kán tì ọ ṣẹlẹ..... that's how you guys always terrify people.....we will fight you like Israel is standing up against your bosses.....you don't know pass intimidation.....tí ìjà ẹṣin bá ṣẹlẹ ni ilé yoruba, ẹ o jẹ pirigidi ìyà
@MorufBello-m1h
7 сағат бұрын
Talohun omo oko nie
@AbiodunAdeosun-t2b
6 сағат бұрын
Eniyan a le ja fun Olorun bi?. Ki lo se eyin Musulumi yi to je wipe Oro jagidijagan ki kuro loro yin. Why are you fighting for God. Is it God that ask you to tell them to apologize. Enikeni ko le ja fun Olorun Olodumare. Let peace reign
@StephaneMoise-n8t
5 сағат бұрын
Olriburuku awon eniyan yi ki lo de ti won mon paio 'a
@jemilaagbaje6238
7 сағат бұрын
Wahala wa nle toyeki gbogbo yin mojuto Olorun ati anabbi len gbinja ,Oba tiose gbinja sini Olodumare
@helenahmed9189
7 сағат бұрын
Kini won so, kanti kanti. Awon ti won soro Yi na won ti daran. Alfa Yi ko ki n se Yoruba. Omo Fulani ni. Awon Yoruba ki won daju SI gbogbo won ki won le won kuro larin wa. Lati abaye wa, Aborisha, Kristieni ati Imole won gbe ni isokan ati alafia. Iya nla mi Aborisha ni. Iya iya mi ni Kristieni. Iya nla mi fi ominira fun iya iya mi lati di onigbagbo. Freedom and unity is the fabric of Yoruba people.
@dashmayortv
8 сағат бұрын
Don’t mind this Alfa he’s only look for publicity even when people hail chief Sunday Adeyemo Anobi tiwa he always say no he’s not Anobi,don’t mind him he’s blabbing
@AYEKOOTOTV812
8 сағат бұрын
Igboho Oosha ko lo ran nise ko kan aye eyin naa ti sope Jesu ji agbado nko
@AdesIfemi
7 сағат бұрын
Eyin Alfa oni eru lori e fi Sunday Igboho Oosha lorun sile o ko ta si yin o e ma ta si o
@billmathias8512
6 сағат бұрын
Anobi iranse ni.oloye Igboho naa lranse Olorun ni
@JimohTijani01
5 сағат бұрын
Awon omo ale ile Yoruba lo fe ko ogun ja awa ọmọ ọkọ Yoruba
@92olamiArabMoney
6 сағат бұрын
Eni Tofẹ́ Yoyin Kuro Ninun Ogun Lehun Gbogun Tii What A Wicked World
@amosomotunde9341
7 сағат бұрын
E tiya were enyin alfa ile yoruba buruku wonyi e kan feda ija esin sile nile yoruba ni e de me tesi ni
@victoriamodupe7896
5 сағат бұрын
SE IWO MO NIWAJU OLORUN ..KO SI ENIA NA TI O.MO NIWAJU ..BABA MI .
@princeayo9513
2 сағат бұрын
Asake ojulowo omo Yoruba, onigele ti ko comon. Dindinrin akindanidani, alainilaakaye ati alaini-arojinle ni gbogbo awon Alfa ilorin wonyi. Se oro esin ni a nso tabi bi iran Yoruba se maa kuro ninu location apanilekunjaye. Se Olorun ni anobi ni? Se eniyan lasan lasan koni anobi ni? Oponu ni Alfa oloriburuku wonyi. Anobi ni Chief Sunday Igboho Oosa je fun iran Yoruba. Iwa lesin,Jesu Kristi ni anobi Christian, Mohammed ni anobi eyin elesin imole,ifa,sango,osun,oya,Late Obafemi Awolowo ati enikeni toba ja fun iran won ni anobi. Awon Christian ko ba elesin kankan ja. Gbogbo awon alfa were yi lo nsaajo yet e ncondemn awon ojise ile Yoruba. Tani Olorun, you're highly appreciated for your boldness and application of wisdom in your response to eranko alfa yii. What's the meaning of anobi? Igboho Oosa is equally more tgan Mohammed lodo temi. Fulani ilorin ni opolopo awon eranko tiwon pera won ni Alfa wonyi meanwhile awon fulani ri yin bi kenferi. What a senseless talk. O ye ki e kolo si Saudi ni eyin oponu, ika ati bunch of illiterate wonyi. Chief Sunday Adeyemo Igboho Oosa the Anobi, the Moses and Messiah of our race.
@jemilaagbaje6238
7 сағат бұрын
Se Sunday lo soro ni ,edakun iru wahala wo ni eyin iran yoruba nhu funrayin gaan,
@FataiAbimbola
5 сағат бұрын
Gbogbo awon elesin tin pa arawon ni Imale, ele gbogbo nwon kuro ni orile Yoruba, ilee Larubawa ni gbogbo nwon gbodo lo maa gbe. Apaniyan ni won. E lo si Mecca, boya won le fuun yin ni iwe igbeluu won. Omo ina ni gbogbo nwon. Awa ko fe apaniyan ni orile edee wa oo. E kuro ni Ilee wa, Olori buruku ni gbogbo yin. Eyi ti e se tito ooo. ❤❤❤❤❤❤ 😂😂😂😂😂😂
@ABDULKARIMSALMAN-d5m
7 сағат бұрын
Tani Olohun Pele Pele dowo re,Ti o ba soro man soro man niwan,pelepele dowo re, pelepele dowo re, pelepele dowo re, pelepele dowo re,
@estherewetuga8245
5 сағат бұрын
Yoruba Nation no going back Abosi awon elesin yi ma wa ga oo Any little thing you have to mae trouble with it Do you have to make trouble with everything you Muslim R lo joko Esu bi kan eyin alatakiti gbogbo yi
@AyotundeOlaoye-wg4bi
8 сағат бұрын
Eku eto
@ABDULKARIMSALMAN-d5m
7 сағат бұрын
Orun meta Leda ma sun,Ronu si Oro Ara re daradara,Tani Olohun ma koja Enu ala,ko si Ohun to to alaafiya,
@musbauadebayo7769
2 сағат бұрын
E ko ara yin lo.e o le fawa sèyin.Iĝboho ni Anobi tiwa.Anobi Larubawa ni tiyiñ.ntele.
@adekunleezekiel2901
3 сағат бұрын
ATI GBO RI,JESU OYINGBO,JESU AGEGE KI NI AWON KIRISTENI SE SI,TORI PE WON MO N TI WON GBA. E JAWO NINU AGABAGEBE.
@aworantisamuel9480
3 сағат бұрын
Awon Alfa to nja fun Anabi you, nwon ki mi emi olorun, eje ki Anabi JA funra re, ki jesu JA fun Ra re , ko si Eni to le JA fun won, Elo Joko staying je.
@estheradepejuoladeji3506
4 сағат бұрын
Ija mekunnu ni oloye Sunday igboho nja. Kosi ounti o je oloye Sunday igboho ju oro awa mekunnu lo. Eyin onibaje, e mo ba oloye Sunday igboho loruko je, kosi oro esin kankan ninu igbese ti oloye Sunday igboho ngbe
@yetundekuti6926
6 сағат бұрын
Ko dara ki a ma ri ise se Airi ise se ni o so wa di ole Oro ti o mu illosiwaju wa fun wa ni ile Yoruba ko ye ki a ma so
@rajiadeyinkaoyenihun1115
8 сағат бұрын
Alfa ko si enikankan to daran,e lo wa ibi joko si
@victoriamodupe7896
5 сағат бұрын
KI SI OHUN TI OKAN SUNDAY IGBOHO ADEYEMO...PELU ORO RARA TI O MU ..ILE SOUTHWEST OF NIGERIA CITIZENS..ECONOMY GROWTH..NAIRA NI O WO ..COMA..YEN WON.O RI SOLUTIONS SI FEDERAL GOVERNMENT OF NIGERIA CITIZENS..TI TUN NRE IWO..TAXES CIVIL SERVANT. HAJJ YEAR 2025..OMIRAN JO FUN WON AWON OLE VIOLENCE..LAZY PEOPLES. SE WON GBE ESIN LE ORI BAYI ...NILU SAUDI ARABIA AWON SAUDI ARABIA COUNTRY..TI NI ..VISION 2030..FUN ILU WON IJA ANOBI NI EYIN MA BA KIRI..EYIN NI E MO ..ENIA INA ATI ALUJONA. SE EYIN NI ENI ..KEY TO PARADIES LOWO NI...EYIN YAHOO BORROWED RELIGION BUSINESS CENTER WON YI
@NETWORKTVSHOW22
8 сағат бұрын
Alfa ẹ sirious o
@silifatonagun1750
6 сағат бұрын
Ibiti e nba oro lo yi Olohun maje ki ari ibinu Olohun ni ile Yoruba, toripe awon ojise Olohun ti e nfi enu abuku kan lotun losi yi oje nkan buruku gan ni,
@victoriamodupe7896
5 сағат бұрын
MO BE YIN O..E FI.SUNDAY IGBOHO ADEYEMO SILE O..KO NI TIME FUN GBOGBO..IJA ANOBI TI E NBA KA YEN O . PELU HISTORY BOOK AWON.ARABICCOUNTRIES
@OniyideAbidemi-z7u
4 сағат бұрын
Gbenu soun awon eniyan jakujaku e lo wa se se ainise lo nda yin lamu Sunday igboho ki se egbe gbogbo yin e lo Joko ara yin je
@stellaodele5734
3 сағат бұрын
Awon Afa were wo la won eleyi e tu lawani ori won ADO lo ma jabo, ifunpa, igbadi o wa lara won gbogbo e isese na ni kini Afa kan wa nwi, nigbati won jba ara won ja ni mosalasi nse ni gbgogbo wa tu ere, nigbati won ya Aso ara won ifunpa ati Igbadi la ri lara won, awon Afa nte Yanrin se Afa ni yen
@sanitempleprayer472
7 сағат бұрын
Eedi tiwo aarin omo yoruba o afi ki oluwa kogbawa o àmin
@BassirouGouverneurAllade
5 сағат бұрын
Fulani ni awon alufa yen won ki se yoruba rara
@BassirouGouverneurAllade
5 сағат бұрын
Ni odo ti emi oloye sunday igboho osaaa ju anabi Mohamed lo.ko si ore kankan ti anabi Mohamed se fun Iran mi sunday igboho ni anobi ti olorun eledumare ran si wa lati gba Iran mi kuro ni oko eru fulani ona ti o gba ju anobi Mohamed lo ni odo temi ni yen o
@taiwowemimo1856
6 сағат бұрын
Won feda ija esin sile kaba tun le ma ri nkan ran Yoruba nation lafe awon alakatakiti enia Olorun ti juyin lo
@AbigailoyelolaOnifade
7 сағат бұрын
Olorii buruku ni awan afa yi wanti were mesin nibo ni afa yi wa nigbati awan aha re nso si omo leyin Kirieti ti wan soro si awan onisese eyin ota Alafia yi elowase se
@OkeowoTaiwo
6 сағат бұрын
Ooto oro ni tani olorun nso.eku eto Iya mi asake.onikaluku lo ni opinion si ara re,ibi to ba wumi ni mo le gbe enikeni si ni okan mi.adura wa maa gba.yoruba nation now
@victoriamodupe7896
5 сағат бұрын
SE EYIN BI AKOBI ..ANOBI..TANI OMO ANOBI TI O FI SULE NINU AYIE LO NINU YI ..NIBO NI IDILE ANOBI NILE YORUBAS LAND PLEASE KO SI ENITI KO LE BU ..ANOBI ..JESUS..ISESE..GBOGBO WA PATA PATA..NI OMO WON IBATA WON ..KO SI SPECIAL OMO FUN WON NILE AYIE TANI O RI ..ANOBI RI NINU GBOGBO YIN PATAPATA..
@AyotundeOlaoye-wg4bi
7 сағат бұрын
Ko dara bi won se daruko igboho osa ninu Oro yi
@StephaneMoise-n8t
5 сағат бұрын
Se e mon pe omo osan ti popo ba yare ni munsulumi i se
@iloriabiodun9682
5 сағат бұрын
Kijipa Abi ki ni oruko re Ose piri bi piri ESIN
@oladimejiadekolu2839
4 сағат бұрын
Anabi is for trillion people.Apply your wisdom pls,is not for you alone
@OniyideAbidemi-z7u
4 сағат бұрын
Kilo se awon were yi gan an
@saheedsolely1407
7 сағат бұрын
Ilobi ma sujaba ota piyapiya awon alabosi ilorin
@AdejumobiSolomon
7 сағат бұрын
E ma da Ija es in sile o ,ki kaluku loogbeje o ,eni ba wu latija ko looba awon terrorists Ninu gbo ,to lo fe gbeja Olorun ,e looojoko jee o anikara tu gbogbo wa e
@helenadegoke6922
7 сағат бұрын
But everybody's entitled to their own personal opinion why are you trying to drag Igboho Oosa into your matter? Leave the man in peace.
@victoriamodupe7896
4 сағат бұрын
KI OLORUN OBA BA WA PA..GBOGBO AWON..BORROWED RELIGION BUSINESS CENTER..WON YEN TI WON MU ..WA FUN WA LATI FI JI AWON RESOURCES WA..LO FI NTUN ILU TI SE...KI OLUWA OBA BA WA PA GBOGBO WON PATAPATA..RE KURO NILE YORUBAS LAND..ASEGUN KI AWON ..ALALE TI WON FI TE ILE YORUBAS LAND..DO..TI ILE YORUBAS LAND FI NTUNBA TUNSE....KI O LEKE. OMO ALE TI WON MU WA FUN WA ASEGUN
@folakelijoka5365
7 сағат бұрын
Hellos eyin Muslim ewa olorun ri kedamo oluwa wipe kosi enikan tole gbeja olodumare ewo etini wahala ju ensin inu ara yin e o sin olorun e o ti e mo titobi oloun rara oo
@victoriamodupe7896
5 сағат бұрын
SE ERI GBOGBO..RADARADA. TI EYIN ALFA YI NSE NILE ODUDUWA YI TI WON BA BI GBOGBO YIN PATAPATA RE..E WA SI ..WESTERN WORLD COUNTRIES..KI E WA MA SE BAYI NIBE .. KO SI SECURITY NO JOBS NO ELECTRICITY PIPE BORNE WATER NO GOOD ROADS NO BUILT GOVERNMENT SCHOOLS HOSPITALS WITH GOOD EQUIPMENT THERE NO EQUAL RIGHT NIGERIA..MO FOODS NO BETTER FUTURE..FOR OUR LEADERS OF TOMORROW IN YORUBA LAND NAIRA MONEY IN ..COMA OF DOLLARS DEBTS UPON DEBTS LO KUN INU NIGERIA TRESSUARY..ECONOMY NOT GROWTH WON O RI GBOGBO AWON YEN LATI FI SE ..WASIN ..KI ILU NIGERIA COUNTRY TORO MOVE FORWARD
@silifatonagun1750
6 сағат бұрын
e ko tiri ogun Fulani yanju tan, ogun esin loku ti ekoju man bayi
@victoriamodupe7896
5 сағат бұрын
SEBI EYIN NA NI ..JESUS LO JI AGBADO NINU OKO OLOKO EYIN ALAKATAKITI. WAR BORROWED RELIGION.. ELO WA ISE MO ISE ..OLE NTELE ALFA TI E.NBA KIRI DA WAHALA SILE..KAKIRI THE WHOLE WORLD PLEASE E TI BA MUSLIMS BORROWED RELIGION JE..KAKIRI AGBALAYE..
@BassirouGouverneurAllade
5 сағат бұрын
A t'igba ti awon fulani ti npa awon eniyan wa ni ile yoruba yi.eniyan melo ni anobi Mohamed ti gba sile.oloye sunday igboho osaaa nikan ni a ri ti o nja fun wa ao ri anobi Mohamed,ona ti oloye sunday igboho osaaa fi ju anobi Mohamed lo niyen
@elevatorlatuns
4 сағат бұрын
Who is the Anobi they are fighting for. Is it Mohammad they are talking about. Absolute nonsense !
@oladimejiadekolu2839
4 сағат бұрын
The man has a big problem he should go for medical test
@OlufunkeFajimolu
3 сағат бұрын
Se oro niye, alakatakiti niwo, Fulanis npa enia ni ilorin, kini won se si. Gbogbo oba loti salo ninu ilu, won fetan le, nwon pa lapalapa.Alfa komadun nikan ni olododo ninu awon alfa ton soro yen.
@akanfeajayi7706
2 сағат бұрын
Ejowo kin nkan toun se awon alfa wonyi,tenu won njo belebele bayi gan,se olorun pe e pe koma ba oun so eni Toba soro oun leyin koma ja fun oun ni,iru awon elesin iya wo niyi gan,bi won ba peyin ni elesin jagidi Jagan,NSE lemama tu bi ejo,Kini nkan toun seyin gan,kelo panu yin mo,ko silu temaa wa tilu na maa toro.
@beckyaanu7034
8 сағат бұрын
Ti won ba bu esin mi emi naa à bu esin won
@joelbalogun9254
4 сағат бұрын
Abi amukunmeko oloriburuku were ni alfa to nso isokuso nipa pe ki enikan wa debunk oun to so pe Igboho niyi lowo oun ju Anabi Mohammed lo.
@StephaneMoise-n8t
5 сағат бұрын
Aaaaaa Eyin eniyine je lo Sun ke ronu
@victoriamodupe7896
5 сағат бұрын
GBOGBO YIN PATAPATA O NI ITIJU NI..TI E BA NI ITIJU..O YE KI GBOGBO YIN PATAPATA. .TI KURO NILU ..ELEBO. ELEBO..KI E KO ARA YIN PATA PATA. LO SILE MIMO KI E FI AWON....ELEBO SILE.NILE.BABA NLA WON ..EYIN NI E SE AFI OJU RA WA.NSE..BORROWED RELIGION BUSINESS CENTER YIN. NILE ELEBO SE ERI ARA SAUDI ARABIA NILE ELEBO BITI YIN ..OLOJUKOKORO ZI E NGBA OWO LOWO AWON ELEBO NI IBI ..ODE INAWO. E NGBA OWO EBO NI PARTY..OLORUN OBA NA MA PA INA AWON..TI WON NFI ESIN.MUSLIM.NA SE BUSINESS CENTER NA ..RE PATAPATA NILE SOUTHWEST OF NIGERIA CITIZENS. AMIN NA RAYABI.
@oladimejiadekolu2839
5 сағат бұрын
Nobody can fight for God.The man should stop nonsense.Are you the Anabi.What is your problem
@beckyaanu7034
8 сағат бұрын
Awon alfa ilorin ni Awon eru larubawa oni wahala promax
@NETWORKTVSHOW22
8 сағат бұрын
Awon ti koda ninu musulumi ni won fe da wahala sile
@silifatonagun1750
6 сағат бұрын
Eyin Alfa, ejowo tori Olohun emun oju kuro nipa ti Oloye Igboho, oro ko kan Oloye Igboho rara, toripe Igboho ko bawon lowo si ija esin rara, Igboho ki se eniyan beyen, Igboho kiyaju si enikeni katowa sope oma so isokuso si ojise Olohun
Пікірлер: 85