Ife esin aniju n je ki awon alfa puro: they say Anobi Yisa is not coming back! they claimed there is no prophet between Yisa and Muhamed. They lie nowadays.
@user-zv3fb2jw5w
20 күн бұрын
We Muslims believe Anobi Isa is coming back !! Just because someone who doesn’t have knowledge about Islam said so doesn’t mean that we all Muslims believes in that. Anobi Isa (Jesus) is coming.
@TheGreatestAlmight
19 күн бұрын
surat Ibrahim (14:4) Never have We sent a Messenger but he has addressed his people in their language that he may fully expound his Message to them. (And after the Message is expounded), Allah lets go astray whomsoever He wills, and guides to the Right Way whomsoever He wills. He is the All-Mighty, the All-Wise.
@gbengakolade6366
20 күн бұрын
Bi a ba ti nṣe eto Yoruba, ko ni iwulo kan kan lati ma fi èdè lárùbáwá bẹrẹ. Gbogbo nkan ti ẹ sọ ni lárùbáwá yẹn ni ẹ le sọ ni ede Yoruba. A wá le ri ki lárùbáwá fi èdè Yorùbá bẹrẹ eto ti wọn bí? Ki Olorun ko gba wa kuro ninu ifira ẹni sí abẹ ẹrú lárùbáwá. Èdè kii se ẹsìn, oju iṣe ati ìhùwà bi Ọlọrun ni ẹsìn, kii se ede rara. Lati gba ominira ni ilẹ Yoruba, a ni sẹ se. Agbudo ya ede ati ise Yorùbá kuro ninu ẹsìn. Ti ẹba dé inu mọsalasi, ele ma ṣọ ede lárùbáwá níbẹ bo bá wù yín. Sugbon asiko ti to ki a ma fi èdè Yorùbá kirun lọwọ ti a wa yi.
@marthinswalemark9673
20 күн бұрын
you are right
@user-tw4su1gk7d
4 күн бұрын
Iropo lorisiirisii ti awon Imole maa npamo Momodu, Eniti koleko, tikoleka koda boya lole ko oruko arare debiti yowakowe qurani kankan. Koda awon Arabu paapa mope awon Imole man awon exaggerate nipa momodu tiwonsi moparo ohunti kolese laye ohun titidi ayeoni. Awon Arabu tinsi Al Lah since time immemorial. Al lah kise Olorun Olodumare ti awa Yooba Omo Alade o, ayato sirawa patapata. Al Lah Saudi ti Arabu is a crescent 🌙 moon/Osupa tawon Arabu maa ng sin, tosibi omo obirin meta eg: Al Lat, Al Uzza & Menat. Orisiirisii atrocities ni Muhammed commit nigba aye re bikofe omo obirin odun mefa losing lopo tabi baa sun ni omo odun mesan @54 nigba tohunje bi grandpa 54 yrs old, Koda otun gbayawo Zainab lowo Zayd omore, orisiirisii iwa itiju t’oun iwa ibaje po pupo lowore. Wo afi kafowo leran kasi maa wo ni.
@tulatuns
20 күн бұрын
Bless you, Baba- YORUBA NATION NOW
@VictoriaKehinde-up9xn
20 күн бұрын
Weldone sir, May God bless you!!!!
@KehindeoseniSaliman-ou4jt
20 күн бұрын
Eku ise takun takun sir ooo babà WA sokoti gbogbo awon OTA yin ma ma Ku ikuojiji tomotomo won ni ooo ni agbara gbogbo awon ALA Len Ile Yoruba patapata ASE gun ooo
E ku eto baba Sokoti ati Imam wa. Olorun a ma fi imo kun imo fun yin. Amoran mi pe o ye ki alfa tabi awon Musulumi ti o ba fe soro anobi ki won ma so inu hadith tabi iwe ti a ti le ri gbogbo oun ti won ba nko wa nipa anobi
@Infidel-r9h
20 күн бұрын
😂😂😂
@oluwafemisanusi3122
20 күн бұрын
@@Infidel-r9h please if you know the exact Hadith please kindly share and don't be using 'f' word
@Infidel-r9h
20 күн бұрын
@@oluwafemisanusi3122 I laugh because you're very correct 🤣 👍
@Saeed.Yousuf-Owusu
18 күн бұрын
There should be no reason why religion should cause dispute among Muslim and Christian Here are some of the key hadith that mention Jesus (Isa) in Islam: Sahih al-Bukhari, Volume 3, Book 43, Hadith 656: By Him in Whose Hands my soul is, surely (Jesus,) the son of Mary will soon descend amongst you and will judge mankind justly. Sahih Muslim, Book 1, Hadith 293: The Messenger of Allah said: I am the nearest of all the people to the son of Mary, and all the prophets are paternal brothers, and there has been no prophet between me and him. Sunan Ibn Majah, Book 36, Hadith 4080: There is no prophet between me and him, that is, Jesus son of Mary. Sahih al-Bukhari, Volume 4, Book 55, Hadith 658: The Son of Mary will soon descend amongst you as a just ruler.
@TheGreatestAlmight
19 күн бұрын
surat Ibrahim 14.4.1
@user-zv3fb2jw5w
20 күн бұрын
Can i call you about this program in the morning sir. I have somethings to say to you and enlighten you about some things
@ifatedoopalaja9423
20 күн бұрын
I know this man, he is also a Nloku iraye son from Lisa Odegbo from ilisan
@ainaakanbi919
20 күн бұрын
Avon wo ni alfa yi npe ni ‘elebo’?
@ainaakanbi919
20 күн бұрын
Se esin Islam yi, Olorun ti nwon nsin ko gbo ede ti Iya tobi won so tofi je wipe ede arabic ni nwon fi nba Olorun soro? Olorun Islam ko gbo Yoruba.
@adenikeayinla5231
20 күн бұрын
In one of the Hadith of our holy prophet SAW. One day our noble prophet was in the midst of his companions a man non believer came into the mosque and urinated the companions wanted to rush the man and he our noble prophet said they should allowed him to finished what he was doing and he later got up and washed the urine. This is to buttress the Ustaz point … ESIN ISLAM ESIN ALAAFIA NI.
@yusufmorayo8542
20 күн бұрын
😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂
@Saeed.Yousuf-Owusu
20 күн бұрын
It is a lie Alfa the Deborah guy was framed because a guy tried to woo her and she decline and the guy and his friends sey her up with a school whatsapp group for studying which they throw the Islam question at her she never cursed Mohammed her friends who are also in the same group with her in the platform told her parents before they left for porthacourt that they lied against her because she didn't want to date a Muslim guy in her class. There are other cases in North where people have been lynched and killed just because they know there are lots of religion extremists who are taught in the Koran to murder anyone who speak ills of Mohammed. It is a pity we have lots of Muslims who are saying deterogary words to Jesus Christ online and even in we have yoruba actors who make jests of Jesus in Yoruba film likes of comedians and Some A-list Actors.
@OlamilekanOguntomi
19 күн бұрын
Baba sokoti eku eto,kotu ojire ni ooo,ki se karo ojire ooo
@Adebayo0147
19 күн бұрын
lol Islam and lie na 5&6 😀😃😃😃
@racheldavis2554
18 күн бұрын
I Dey tell u
@otunba59
19 күн бұрын
A dupe fun eni e mu wa. Mo fe pe yin akiyesi kan ni. Ki a ma Onisese ni Elebo ede abuku ni fun awa Yoruba ti a yan Isese laayo. E jowo Baba Sokoti eyin e pe wa pelu ohun ti a gbagbo - ONISESE NIWA a kin se Elebo. Awon Alafa ati Woli ti won gbe awo lo si orita meta nko?
@racheldavis2554
18 күн бұрын
We should not be ashamed for calling elebo because we are
@otunba59
18 күн бұрын
@@racheldavis2554 which of the world religion is not elebo? The masses celebrated at the Catholic Church are sacrifices. Kill of rams during Ileya is sacrifice. We of the Traditional Religion are not the only ones making sacrifices. All religion practitioners are Elebos. We are ONISESE or ELESIN IBILE. Islam referring to us as elebo is derogatory e belittling.
Пікірлер: 38