Sheik eyin naa eko ni fun yin Lori iku sheik aboto, awon oun ti ema nso nipa ibadah awon Muslim yio ku tiwon bati je awon jomoh yin.won mose asiri tin bo loju aye baba Yi sugbon ni igbeyin nko olohun tuu sita.eyin na ejekoje lilahi warosulihi ni gbogbo oun ti e nso,Tori orisirisi na lati gbo nipa yin.Abu rahimo so orisirisinipa yin, sugbon oje otito koje otito gbogbo na ni ao mo boya lilahi warosulihi ni gbogbo oun ti a ma nso nipa ibadah awon Muslim Miran.
Пікірлер: 9