Ní ìgbà kan, Ìjàpá àti Ajá jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́. Ìyàn mú ní ìlú wọn, èyí sì ṣe àkóbá fún gbogbo ẹranko àyàfi Ajá nìkan. Ìjàpá tọ ọ̀rẹ́ rẹ̀ Ajá lọ láti wá ọ̀nà-àbáyọ. Ǹjẹ́ Ajá ràn án lọ́wọ́ bí? Kí ló ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn náà? Ẹ wo fídíò yìí láti mọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀.
Time code
0:00 - Orin ìṣíde
0:45 - Ìfáàrà: Bàbá Apàlọ́padídùn bẹ̀rẹ̀ ìtàn sísọ pẹ̀lú àwọn ọmọdé náà
1:30 - Ìjàpá àti ìyàwó rẹ̀ Yánníbo
2:16 - Ìjàpá ní ilé Ajá
5:22 - Ìjàpá nínú ilé rẹ̀
5:31 - Ìjàpá nínú ilé Ajá
5:49 - Ìjàpá àti Ajá lọ́nà oko
7:01 - Ìjàpá àti Ajá nínú oko
8:03 - Ìjàpá àti Ajá lọ́nà oko
8:40 - Orin
10:15 - Ìjàpá àti Bàbá Àgbẹ̀
11:20 - Ìjàpá àti Bàbá Àgbẹ̀ ní Ààfin Ọba
11:57 - Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Ọba lọ́nà ilé Ajá
12:18 - Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Ọba nínú ilé Ajá
12:40 - Ìjàpá àti Ajá níwájú Ọba
13:26 - Àwọn Ẹ̀kọ́ tí a rí kọ́ nínú ìtàn náà
15:50 - Ìdúpẹ́
#yoruba #cartoon #folktales #stories #story #tale #toon #tortoise #folklore #aloyoruba #itan #animation #animations #folktale #folklores #alo #ijapa #yorubaanimation #yorubafolktale #yorubafolklore #yorubacartoon #yorubacartoons #yorubaanimations #yorubafolktales #yorubafolklores #aloijapa #storytelling #africanfolktales #africa #african #yorubafolktales #yorubafairytales #nigerianfolktales #africanfolktales #bedtimestories #kidsongs #cocomelon #peppapig #moonbugkids #firsttoons #billionsurprisetoys #wbkids #sokids #jjsanimaladventures #ijapaologbonewe #ijapayorubamovie #aloijapa #yorubatv #viral #youtube #youtubechannel #subscribe #yorubavideo #video #kidstv123 #yorubanimi #yorubarewa #koyoruba #speakyoruba #yorubapeople #yorubarace #youtubetrending #trending #king
Негізгі бет Ijapa ati Aja | Yoruba | Not Subtitled
Пікірлер