Ìtàn yìí dá lórí àwọn ọmọdékùnrin mẹ́ta tí wọ́n ń tiraka láti leè rí ọwọ́ mú lọ sẹ́nu. Àwọn ni wọ́n ń tọjú ìyá wọn tó ti darúgbó. Ìjàpá Ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́ ta mọ́ òfin ọba lọ́nà láti leè ti ọwọ́ àwọn ọmọ náà bọ ṣọ̀ọ̀lọ̀, kí o lè ti ipasẹ̀ èyí sọ ara rẹ̀ dí olówó. Níbo ni ẹ lérò pé ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ ìyá mẹ́ta yìí àti ìyá wọn yóò já sí? Níbo ni ẹ lérò pé ète Ìjàpá yóò yọrí sí ? Ẹ wo fídíò yìí kí ẹ lè mọ ohun ti ó ṣẹlẹ̀. Ire o!
#yoruba #cartoon #folktales #stories #story #tale #toon #tortoise #folklore #aloyoruba #itan #animation #animations #folktale #folklores #alo #ijapa #yorubaanimation #yorubafolktale #yorubafolklore #yorubacartoon #yorubacartoons #yorubaanimations #yorubafolktales #yorubafolklores #aloijapa #storytelling #africanfolktales #africa #african #yorubafolktales #yorubafairytales #nigerianfolktales #africanfolktales #bedtimestories #kidsongs #cocomelon #peppapig #moonbugkids #firsttoons #billionsurprisetoys #wbkids #sokids #jjsanimaladventures #ijapaologbonewe #ijapayorubamovie #aloijapa #yorubatv #viral #youtube #youtubechannel #subscribe #yorubavideo #video #kidstv123 #yorubanimi #yorubarewa #koyoruba #speakyoruba #yorubapeople #yorubarace #youtubetrending #trending
Timecodes
0:00 - Orin Ìṣíde
0:41 - Ìfáàrà: Bàbá Apàlọ́padídùn bẹ̀rẹ̀ ìtàn sísọ fún àwọn ọmọdé náà
1:27 - Àwọn ọmọdékùnrin mẹ́ta níwájú ìyá wọn
2:58 - Àwọn ọmọdékùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ń ta ayò níwájú ilé wọn
4:33 - Ìjàpá fi ẹ̀sùn kan àwọn ọmọ yìí pé wọ́n tàpá sófin ọba
5:10 - Ìjàpá wọ́ àwọn ọmọ mẹ́tẹ́ẹ̀ta dé iwájú ọba
7:40 - Àwọn ọmọ mẹ́tẹ́ẹ̀ta ń sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ sí wọn fún ìyá wọn
8:25 - Àwọn ọmọ mẹ́tẹ́ẹ̀ta bẹ̀rẹ̀ sí ní múrasílẹ̀ de ọjọ́ ìdíje
9:03 - Ọjọ́ ìdíje
9:38 - Ìdíje àkọ́kọ́ wáyé létí-òkun
10:06 - Orin kìíní
11:16 - Ìdíjé èkejì wáyé nídìí igi ọ̀pẹ tó ga jùlọ
11:31 - Orin kejì
12:43 - Ìdíje kẹta wáyé ní ààfin ọba
13:48 - Orin kẹta
14:01 - Àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba ń mú Ìjàpá lọ sí ẹ̀yìn-odi ìlú fún ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀
14:32 - Àwọn ẹ̀kọ́ tí a rí kọ́
16:52 - Ìdúpẹ́
Негізгі бет Ijapa ati Omo Iya Meta | Yoruba | Not Subtitled
Пікірлер