Èyí jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe pàtàkì lórí Ìtàn ìlú Ọ̀yọ́ àti àwọn ìlànà tí ó rọ̀ mọ́ yíyan Àláàfin, níbi tí a ti ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú Olóyè M.O. ÒGÚNMỌ́LÁ tí wọ́n jẹ́ Ọ̀tún Ọ̀yọ́ àti Olùdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ Ládìgbòlú Grammar School ní ìlú Ọ̀yọ́.
Ẹ má gbàgbé láti darapọ̀ mọ́ wa lójú òpó KZitem (Subscribe) yìí láti máa gbádùn àwọn ohun Ìṣẹ̀dálẹ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Yorùbá àtàtà.
Негізгі бет OLOYE M.O. OGUNMOLA (OTUN OYO ATI OLUDASILE ILE EKO LADIGBOLU GRAMMAR SCHOOL, OYO)
Пікірлер: 30